Ẹ̀kọ́ Ẹ̀rọ jẹ́ agbára ìtòlẹ́sẹẹsẹ kọ̀ǹpútà tàbí ẹ̀rọ láti kẹ́kọ̀ọ́ nípasẹ̀ dátà tí a pèsè àti láti ronú fúnra rẹ̀ láìsí ìtòlẹ́sẹẹsẹ ní pàtó. O jẹ ohun elo ti AI (Oye Oríkĕ).
Machine learning is the ability of a computer program or device to learn through the data provided and to think for itself without a specific program. It is an application of AI (Artificial Intelligence).
This is proudly brought to you by @rollascriptings and presented by @STEMInstructor_